African Languages
-
Ẹṣọ́ra o! Ẹ má ṣe tẹ àtẹ̀jísẹ́ sí ilà fóònù 8014, bí ẹ ṣe lè ṣe àrídájú ibùdó ìdìbò yin lóri ayélujára rèé
Àhésọ: Kí olùdìbò lè ṣ’awari ibùdó ìdìbò rẹ, tẹ àtẹ̀jísẹ́ pẹ̀lú nọ́mbà mẹsan orí káádì ìdìbò alálòpé rẹ ránṣẹ́ sí…
Read More » -
Ìdìbò ọdún 2023: ìbéèrè mẹwàá nípa àyẹ̀wò orúkọ ati ìdìbò ni ọjọ ibo
Ti a ba gbe iwa ìbàjẹ́ sapa kan, ailemuilerise ati awọn oun míràn, àìní ìmòye nípa ètò ìdìbò jẹ ọkan…
Read More » -
Àlàyé: Ẹ̀tọ́ àti idojukọ àwọn àkàndá ẹ̀dá l’ásìkò ìdìbò ní Nàìjíríà
Ẹ̀tọ́ àwọn àkàndá ẹ̀dá ṣe pàtàkì nínu ètò ìdìbò. Ni orílè-èdè Nàìjíríà, awon àkàndá ẹ̀dá maá ń saba kojú ìṣòro…
Read More » -
Fun Ìdìbò ọdún 2023: Mọ nípa ẹ̀tọ́ re gegebi olùdìbò l’ọjọ́ ìbò
Láìsí ìyípadà airotẹlẹ bíí ti ìdìbò odun 2015 àti 2019, olùdìbò mílíọ̀nù merinlelọgọrin (84 million) ni wọ́n fi orúkọ sílẹ̀…
Read More » -
Òdodo ọ̀rọ̀! Orílè-èdè Nàìjíríà ni ó ń ṣe iṣẹ́-ọ̀gbìn ìrẹsì jùlọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀
Àhesọ Olùrànlọwọ pataki fún ààrẹ Muhammadu Buhari l’órí ètò ọ̀rọ̀ awujo, tí ó sì tún jẹ́ igbákejì agbẹnusọ fún ikọ̀…
Read More » -
Ìwà ọ̀daràn nípa ètò ìdìbò tí ẹ gbọ́dọ̀ mọ̀ ṣáájú ìdìbò ọdún 2023
Ní ọdún 2022, ètò ìdìbò gómìnà ti wáyé ní ìpínlẹ̀ méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní orílẹ-èdè Nàìjíríà: ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun àti Èkìtì. Botilẹjẹpe…
Read More » -
Bẹẹni! Eniyan lè máa jẹun dáadáa kí ó sì ní ọgbẹ́-inú
Àhesọ: Ènìyàn tó bá jẹun dáadáa, kò lè ní ọgbẹ́-inú. Aṣinilọ́nà ní àhesọ yìí: Botilẹjẹpe bí ènìyàn bá kọ̀ látì…
Read More » -
Steve Harvey ò wá sí Nàìjíríà láti wá ṣe ìpolongo ìdìbò fún Peter Obi
Ọ̀rọ̀: Aṣàmúlò ìtàkùn ìbáraenidọ́rẹ̀ẹẹ́ Facebook kan wípé gbajúgbajà atọkùn ètò tẹlifíṣàn ní ìlú Amẹ́ríkà, Steve Harvey, tiwà ní Nàìjíría láti…
Read More » -
Osinbajo ba ya raba wa ‘yan Najeriya tallafin dubu 33
Zargi: Wabi sakon WhatsApp na zargin wai mataimakin shugaban kasar Najeriya, Yemi Osinbajo na rabawa ‘yan Najeriya tallafi na nera…
Read More » -
Ana iya haihuwar jarirai da hakoransu a cike?
Zargi: Wata mai amfani da shafin soshiyal mediya na zargin wai ta haifi jariri mai hakora a cike. Akwai tatsuniyoyi…
Read More »