Yoruba
-
Iro ni o! Kí ènìyàn kọ́kọ́ dà omi s’órí ni baluwe ò lè fa ààrùn rọpárọsẹ̀
Aheso: Olumulo ikanni ibaraẹnisọrẹ Facebook sọ wípé eniyan lé ni ààrùn rọpárọsẹ̀ lẹ́yìn tí ó bá tẹ̀lé àwọn ìlànà kan…
Read More » -
Ṣé èepo ògèdè wẹ́wẹ́ lè mú kí eyín ènìyàn funfun lesekese?
Ahesọ: Inú eepo ògèdè lè fọ eyín ènìyàn mọ, kódà yòó funfun balau. Àbájáde ìwádìí: Kò sí ẹrí tó dájú.…
Read More » -
Iro ni! Olori ijọba ologun tẹ́lẹ̀rí, Gowon ò kú o
Ahesọ: ìròyìn akalekako kan lo gbe aheso kan pé olori ijọba ologun nigba kan ri lorilẹede Naijiria, Ọgagun fẹyinti, Yakubu…
Read More » -
Se lóòtọ́ ni ààrẹ Tinubu fẹ́ fi owó dọ́là rọ́pò Náírà?
Ahesọ: Olumulo ikanni ibaraẹnisọrẹ Facebook ṣ’atunpin fọ́nrán kan to ṣafihan ibi ti ààrẹ Tinubu ti kede ìgbésẹ̀ lati fi owó…
Read More » -
Ǹjẹ́ àjọ NDLEA yan Naira Marley sípò aṣojú?
Awọn olumulo ẹ̀rọ alatagba ń fi abuku kan Náírà Marley àti ile-ise orin, Marlian Music, lórí ikú Mohbad. Bí awọn…
Read More » -
Ṣé idoti ati ìwà ọ̀bùn ló ń ṣ’okunfa àkóràn ojú ara obìnrin? Oun tí o ní láti mọ̀ rèé
Àwòrán to ṣàpèjúwe àkóràn ojú ara obìnrin Orísun àwòrán: Dr Mona
Read More » -
Njẹ a lè fi tòmátì ati aáyù fọ asẹtọ ọmọkunrin mọ́?
AHESỌ: Ojú òpó kan lórí ìkànnì ibaraẹnisọrẹ Facebook gbe ahesọ kan pé tòmátì ati garlic/aáyù lè fọ asẹtọ ọmọkùnrin mọ́.…
Read More » -
Òdodo ọ̀rọ̀, ọtí afunnilokun lè ṣe ijamba fún ìlera ara ènìyàn
AHESỌ: Ọtí afunnilokun le ṣe ijamba fún ikùn, ó lè mú ki ẹ̀dọ̀kí wú, o lè dín ọpọlọ, o sì…
Read More » -
Ayédèrú ní àwòrán to ṣàfihàn Peter Òbí ni ilé ìjọba Nàìjíríà
AHESỌ: Ọgbẹni Peter Òbí lọ ṣe àbẹ̀wò sí ààrẹ Bọla Tinubu ní ilé ìjọba Nàìjíríà, Aso Rock, ti ìlú Abuja. …
Read More » -
Iro ni o! Ààrẹ orilẹ-ede Nàìjíríà tẹlẹ ri, Obasanjo ò kú o
AHESỌ: Ààrẹ orilẹ-ede Nàìjíríà nigba kan ri, Olusegun Obasanjo ti di olóògbé. ÀBÁJÁDE ÌWÁDÌÍ: Iro ni! Ìwádìí wà àti ìfòròwánilénuwò…
Read More »