Ahesọ: Èlò álọ́ọ́mù jẹ oun kan ti obinrin le lo si oju abẹ́ ki o le kórajọ...
Yoruba
Àlùfáà Chris Oyakhilome, laipẹ yii gba awon ọmọ ijọ re niyanju pe ki won ko imoran dokita...
Aheso: Express, ojú òpó kan lórí ikanni ibaraeniṣọrẹ, Facebook gbe ahesọ pe alaga àjọ eleto ìdìbò INEC,...
Aheso: Atejade kan ti won tan ka ori ikanni Whatsapp salaye pe bébà ìgbọ̀nsẹ̀ le fa akoransi...
Aheso: Olumulo ikanni ibaraẹniṣọrẹ Facebook sọ wipe ilumọọnka olorin Ebenezer Obey-Fabiyi ti pakoda. Abajade iwadii: Iro nla!...
L’aipe yi, ìjọba àpapọ̀ polongo pé wọ́n yoo bẹrẹ sii ṣe idanilẹkọ àwọn ọmọ orileede Naijiria l’ori...
Àhesọ: Olumulo ikanni ibaraenisore Facebook so wipe arakunrin Adedeji Adeleke ti kọ lakọ pari ileeṣẹ amunawa re...
Àhesọ: Aṣàmúlò X kan sọ pé ìdá àádọ́rin nínú ọgọ́rùn-ún (70 per cent) àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà...
Ahesọ: Arakunrin kan lori ikanni ibaraenisọrọ X sọ wipe o ṣeéṣe ki lilo oogun ìfètòsọ́mọbíbí lọpọ igba...
Ahesọ: Olumulo ikanni ibaraeniṣọrẹ Facebook sọ wípé oludari ìjọ mímọ́ àgùdà, póópù Francis ti jade láyé. Abajade...
