Yoruba
-
Òye àtọwọ́dá ni wọn fi ṣ’ẹda àwọn fọnran akalekako ori ikanni TikTok wọnyi ti o ṣ’eleri owó iranwọ
Ahesọ: Àwọn fonran kan gbode kan lori ikanni TikTok, ede abinibi Hausa ati Yoruba ni wọn fi se, àwọn eniyan…
Read More » -
Ǹjẹ́ Trump ṣèlérí láti dènà ìdìbòyan Tinubu l’ọ́dun 2027?
Àhesọ: Aṣàmúlò Facebook kan, @Onyee Arangee, sọ wípé Ààrẹ orílẹ-èdè Amẹ́ríkà Donald Trump fẹ́ lọ́wọ́ sí ìdìbò Nàìjíríà tó ń…
Read More » -
Surrogacy: Àwọn alagbabi ṣ’alaye bi ìkànnì ibaraẹniṣọrẹ, ìròyìn ofege ati àìlòfin ṣe ṣ’àkóbá fun wọn
Ní ìgbà tí arabinrin Temitope Afolabi rii wípé ọkọ rẹ̀ le ṣ’ẹwọn lórí gbèsè miliọnu mejidinlaadọta náírà, ni o ba…
Read More » -
Iléẹjọ́ kan ni ki arabinrin yii san owó ìtanràn leyin ti o kọ̀ lati ṣ’abewo si okunrin to fun ni owó ọkọ̀. Kini òfin sọ?
Tita omonikeji lọọre jẹ oun kan pataki ninu ìbáṣepọ̀ ọmọ eniyan, paapaa laarin awon ti wọn jẹ́ ololufẹ. Biotilejepe itaniloore…
Read More » -
Irọ́ o! Àwọn ènìyàn kò máa f’okùn sọdá odò ní Nàìjíríà, bí fídíò kan ṣe ṣàfihàn
Àhesọ: Asare Obedi pín fọ́nrọ́n kan lórí Facebook, èyí tí ó ṣàfihan obìnrin kan tó ń gun òkùn láti sọdá…
Read More » -
Irọ́ ni! Ìwé ìrìnnà orílẹ̀-èdè Yorùbá kò ní ìdánimọ̀ òfin, wọn kò gbẹ́sẹ̀lé ìwé ìrìnnà Nàìjíríà
Àhesọ: Koiki Media tẹ àtẹ̀jáde kan wípé àwọn orílẹ̀-èdè l’ágbàáyé ti ń gbẹ́sẹ̀lé ìwé ìrìnnà orílẹ-èdè Nàìjíríà. Bákannáà, ó wípé…
Read More » -
Ṣe òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ pe ara eniyan ni ọkàn méjì?
Láípẹ̀ yii, olumulo ikanni Facebook, From Quarks to Quasars, sọ wipe ara eniyan ni ọkàn keji, isalẹ ẹsẹ̀ lo si…
Read More » -
Ṣọ́ra o! Ìjọba àpapọ̀ ò fun enikeni ni ẹ̀bùn owó lati ṣ’etọ́ju idile
Aheso: Atejade kan ti won satunpin lori ikanni ibaraenisoro WhatsApp gbe aheso pe ìjọba apapo n bun omo orileede Naijiria…
Read More » -
Òdodo ọ̀rọ̀! Àìrórunsùn le fa ikú àìt’ọ́jọ́
Aheso: Olumulo ikanni X, @Fact sọ wípé eniyan ti kò ba rẹ’jú tàbí sun oorun botiye, onitoun le fori lugbadi…
Read More » -
Ǹjẹ́ ìhu-ehín ọmọdé le ṣ’ekú pa ọmọ ọwọ́?
Ahesọ: Olumulo ikanni TikTok kan, Ajoke (@harjohkeh001) sọ wípé ìhu-ehín lo ṣ’e ikú pa ọmọ òun. Abajade iwadii: Irọ ni.…
Read More »