Àhesọ: Aṣàmúlò ìtàkùn ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ Facebook kan wípé mímu àpòpọ̀ ewúro àti omi àgbọn yóò pa àrun ẹ̀dọ̀...
Yoruba
Àhesọ: Aṣàmúlò ìkànnì X kan wípé ọpọlọ obìrin má ń súnkì nígbà tí ó bá wà nínú...
Ìròyìn lẹkunrẹrẹ Ọpọlọpọ ànfààní lo wa lara èso apálá/kùkúńbà, èso náà ko ni kálórì púpọ ṣùgbọ́n ó...
Àhesọ: Ṣúgà ma ń fa ẹ̀jẹ̀ ríru sí ara ènìyàn ju iyọ̀ lọ. Àbájáde Ìwádìí: Àhesọ yìí...
Iroyin lẹkunrẹrẹ Oríṣiríṣi agbekale ilana imototo lo tẹ̀lé àjàkálẹ̀ ààrùn COVID-19, biotilẹjẹpe òmíràn kò bójúmu. Òkan lára...
Àhesọ: Aṣàmúlò ìkànnì Facebook sọ wípé jíjẹ ọ̀gẹ̀dẹ̀ òmìnì tàbí àgbagbà èyí tí àwọ rẹ̀ ní àbàwọ́n...
Aheso: Ààrẹ Tinubu bu ẹnu àtẹ́ lu ìwádìí ti BBC gbé jáde l’órí olóògbé oníwàásù T.B. Jóṣúà. ...
Láìpẹ́ yìí, ìbúgbàmù kan mi Bódìjà ni ibile ariwa tí Ibadan, ìpínlè Óyo. Ninu atejade kan, agbẹnusọ...
Aheso: A lè fi kanafuru àti ata ilẹ̀ fọ ilé ọmọ obinrin. Àbájáde ìwádìí: Irọ́ ni! Àwọn...
Ahesọ: Àwọn olumulo èrọ alatagba gbé ahesọ kan pé abẹ́rẹ́ àjẹsára ti a fi n gbogun ti...
