HAUSA
Awọn olumulo ẹ̀rọ alatagba ń fi abuku kan Náírà Marley àti ile-ise orin, Marlian Music, lórí ikú Mohbad. Bí awọn ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà ti n rọ awọn ẹṣọ aláàbò pé kí wọ́n ṣe ìwádìí to péye lórí ọrọ naa, àwọn ẹlòmíràn bu enu àtẹ́ lu NDLEA fún ibaṣepọ won pelu ọgbẹni Fasola (Naira Marley).
Àwòrán to ṣàpèjúwe àkóràn ojú ara obìnrin Orísun àwòrán: Dr Mona